ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 August ojú ìwé 8
  • Àkànṣe Ìwàásù Láti Pín Ìwé Ìròyìn Ilé Ìṣọ́ Lóṣù September

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àkànṣe Ìwàásù Láti Pín Ìwé Ìròyìn Ilé Ìṣọ́ Lóṣù September
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • “Tu Gbogbo Àwọn Tí Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Bí Ọlọ́run Ṣe Ń Tù Wá Nínú
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2016
  • Ìtùnú àti Ìṣírí—Àwọn Ohun Iyebíye Alápá Púpọ̀
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 August ojú ìwé 8

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Àkànṣe Ìwàásù Láti Pín Ìwé Ìròyìn Ilé Ìṣọ́ Lóṣù September

Ilé Ìṣọ́ No. 5 2016 | Ibo Lo Ti Lè Rí Ìtùnù?

Gbogbo èèyàn tó wà láyé ló nílò ìtùnú. (Onw 4:⁠1) Lóṣù September, a máa pín ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ lákànṣe, àkòrí Ilé Ìṣọ́ yẹn máa dá lorí ìtùnú. Ẹ rí ì dájú pé ẹ pín ìwé ìròyìn yìí fún gbogbo èèyàn. Ká tó lè tù àwọn èèyàn nínú, a ní láti rí wọn ká sì bá wọn sọ̀rọ̀, torí náà, a ò ní fí ìwé ìròyìn yìí sí ẹnu ọ̀nà àwọn tí kò bá sí nílé.

OHUN TÁ A LÈ SỌ

“Gbogbo wa la máa ń nílò ìtùnú lọ́pọ̀ ìgbà. Ṣùgbọ́n ibo lẹ rò pé a ti lè rí ìtùnú? [Ka 2 Kọ́ríńtì 1:​3, 4.] Ilé Ìṣọ́ yìí sọ̀rọ̀ nípa bí Ọlọ́run ṣe pèsè irú ìtùnú bẹ́ẹ̀.”

Bí ẹni náà bá nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ wa tó sì gba ìwé ìròyìn náà, . . .

FI FÍDÍÒ KÍ NÌDÍ TÓ FI YẸ KÓ O KẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ? HÀN ÁN

Lẹ́yìn náà, fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ̀ ọ́.

MÚRA RẸ̀ SÍLẸ̀ DE ÌGBÀ TÓ O MÁA PA DÀ WÁ

Bi í ní ìbéèrè tí wàá dáhùn nígbà tó o bá pa dà wá, irú bíi “Kí nìdí tí Ọlọ́run fi fàyè gba ìjìyà?”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́