ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 January ojú ìwé 5
  • Ọlọ́run San Hesekáyà Lẹ́san Torí Pé Ó Nígbàgbọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọlọ́run San Hesekáyà Lẹ́san Torí Pé Ó Nígbàgbọ́
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọba Kan Jẹ Èrè Ìgbàgbọ́ Rẹ̀
    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà—Ìmọ́lẹ̀ fún Gbogbo Aráyé, Apá Kìíní
  • Áńgẹ́lì Jèhófà Dáàbò Bo Hẹsikáyà
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • “Má Fòyà. Èmi Fúnra Mi Yóò Ràn Ọ́ Lọ́wọ́”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • Ọlọ́run Ran Hesekáyà Ọba Lọ́wọ́
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 January ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | AÍSÁYÀ 34-37

Ọlọ́run San Hesekáyà Lẹ́san Torí Pé Ó Nígbàgbọ́

Rábúṣákè àtàwọn ọmọ ogun rẹ̀ wà lẹ́yìn odi ìlú Jerúsálẹ́mù

Senakéríbù Ọba Ásíríà rán Rábúṣákè sí Jerúsálẹ́mù, ó ní káwọn ará ìlú náà juwọ́ sílẹ̀ fún òun. Àwọn ará Ásíríà lo onírúurú ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ láti kó àwọn Júù láyà jẹ, kí wọ́n báa lè juwọ́ sílẹ̀ láìjẹ́ pé wọ́n bá wọn jagun.

  • Àwọn ọmọ ogun Ásíríà wà lẹ́yìn odi ilé Jerúsálẹmù

    Íjíbítì pàápàá kò lè gbà yín sílẹ̀.​—Ais 36:6

  • Àwọn èèyàn ń ṣiyè méjì

    Jèhófà kò ní jà fún yín, torí pé inú rẹ̀ kò dùn sí yín.​—Ais 36:7, 10

  • Àwọn ọmọ ogun Ásíríà

    Àwọn ọmọ ogun Ásíríà lágbára gan-an, ọwọ́ kan ni wọ́n máa pa yín rẹ́.​—Ais 36:8, 9

  • Ilé ńlá kan àti pápá tí wọ́n nǹkan sí

    Ìgbésí ayé yín á dẹrùn tẹ́ ẹ bá juwọ́ sílẹ̀ fún Ásíríà.​—Ais 36:16, 17

Hesekáyà fi hàn pé òun nígbàgbọ́ tó lágbára nínú Jèhófà

37:1, 2, 14-20, 36

  • Ó ṣe gbogbo ohun tágbára ẹ̀ ká láti múra ìlú náà sílẹ̀ de ìsàgatì

  • Ó gbàdúrà pé kí Jèhófà gba àwọn sílẹ̀, ó sì gba àwọn ará ìlú níyànjú láti ṣe bẹ́ẹ̀

  • Ọlọ́run san Hesekáyà lẹ́san fún ìgbàgbọ́ rẹ̀ nígbà tó rán ańgẹ́lì kan láti pa 185,000 àwọn ọmọ ogun Ásíríà lóru ọjọ́ kan ṣoṣo

    Hesekáyà ń gbàdúrà, áńgẹ́lì kan sì mú idà dání
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́