ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 January ojú ìwé 4
  • “Jìófà . . . Ìwọ Ni Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Jìófà . . . Ìwọ Ni Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọba Kan Jẹ Èrè Ìgbàgbọ́ Rẹ̀
    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà—Ìmọ́lẹ̀ fún Gbogbo Aráyé, Apá Kìíní
  • Ó Fún Wa Lómìnira Láti Ṣe Ohun Tó Wù Wá
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • Ọlọ́run Ran Hesekáyà Ọba Lọ́wọ́
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • ‘Ó Ń Bá A Nìṣó Ní Fífà Mọ́ Jèhófà’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 January ojú ìwé 4

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

“Jèhófà . . . Ìwọ Ni Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé”

Hesekáyà ń gbàdúrà

Ó ṣe pàtàkì pé ká gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà lásìkò tó rọgbọ àti nígbà tí nǹkan bá nira. (Sm 25:1, 2) Ní ọ̀rúndún kẹjọ ṣáájú Sànmánì Kristẹni, àwọn Júù tó wà ní Júdà dojú kọ ìṣòro kan tó dán ìgbàgbọ́ wọn nínú Ọlọ́run wò. A rí ẹ̀kọ́ tó pọ̀ kọ́ látinú ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà yẹn. (Ro 15:4) Lẹ́yìn tó o bá ti wo fídíò náà “Jèhófà . . . Ìwọ Ni Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé,” gbìyànjú láti dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:

  1. Ìṣòro wo ni Hesekáyà dojú kọ?

  2. Báwo ni Hesekáyà ṣe fi ìmọ̀ràn tó wà nínú ìwé Òwe 22:3 sílò nígbà tó kíyè sí i pé ó ṣeé ṣe káwọn Ásíríà sàga ti àwọn?

  3. Kí nìdí tí Hesekáyà kò fi ronú pé káwọn juwọ́ sílẹ̀ fún Ásíríà tàbí kí òun wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ àwọn ará Íjíbítì?

  4. Báwo ni Hesekáyà ṣe jẹ́ àpẹẹrẹ rere fáwọn Kristẹni?

  5. Kí lóhun tó lè dán ìgbọ́kànlé wa nínú Jèhófà wò lóde òní?

Kọ àwọn ipò tó o ti lè fi hàn pé Jèhófà lo gbọ́kàn lé jù lọ

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́