Ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀
Àwọn nǹkan rere wo ni Ọlọ́run ṣèlérí fún aráyé? Ṣé o gbà pé òótọ́ lohun tó sọ nínú Ọ̀rọ̀ rẹ̀? Àwọn àpilẹ̀kọ tó tẹ̀ lé e yìí máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn kan lára ìlérí Ọlọ́run àti ìdí tó fi yẹ kó o gbà wọ́n gbọ́. Ó sì tún sọ bó o ṣe lè jàǹfààní àwọn nǹkan rere tí Ọlọ́run ṣèlérí.