ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 January ojú ìwé 6
  • Jésù Fẹ́ràn Àwọn Èèyàn

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jésù Fẹ́ràn Àwọn Èèyàn
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 January ojú ìwé 6
Jésù mú adẹ́tẹ̀ lára dá

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 8-9

Jésù Fẹ́ràn Àwọn Èèyàn

Mátíù orí 8 àti 9 sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ́ òjíṣẹ́ Jésù ní àgbègbè Gálílì. Bí Jésù ṣe wo àwọn èèyàn sàn fi hàn pé alágbára ni, àmọ́ ní pàtàkì, ó fi hàn pé ó láàánú, ó sì nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn gidigidi.

  1. Àwọn ìlú tí Jésù ti mú àwọn èèyàn lára dá ní Gálílì

    Jésù wo adẹ́tẹ̀ kan sàn.​—Mt 8:1-3.

  2. Jésù wo ìránṣẹ́ ọ̀gá ológun kan sàn.​—Mt 8:5-13

    Ó wo ìyá ìyàwó Pétérù sàn.​—Mt 8:​14, 15

    Ó lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, ó sì mú àwọn aláìsàn lára dá. ​—Mt 8:​16, 17

  3. Jésù lé àwọn ẹ̀mí burúkú jáde sáàárín àwọn ẹlẹ́dẹ̀.​—Mt 8:​28-32

  4. Jésù mú arọ lára dá.​—Mt 9:1-8.

    Ó mú obìnrin kan tó fọwọ́ kan aṣọ rẹ̀ lára dá, ó tún jí ọmọbìnrin Jáírù dìde.​—Mt 9:18-26

    Ó la ojú afọ́jú, ó mú kí odi sọ̀rọ̀.​—Mt 9:27-34

  5. Jésù rìnrìn-àjò kárí àwọn ìlú àti abúlé, ó sì ń wo onírúurú àìsàn àti òkùnrùn sàn.​—Mt 9:35, 36

Báwo ni mo ṣe lè túbọ̀ máa ṣàánú àwọn èèyàn, kí n sì nífẹ̀ẹ́ wọn?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́