January Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé January 2018 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ January 1-7 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 1-3 “Ìjọba Ọ̀run Ti Sún Mọ́lé” January 8-14 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 4-5 Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Ìwàásù Jésù Lórí Òkè MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Báwo Lo Ṣe Lè Kọ́kọ́ Wá Àlàáfíà Pẹ̀lú Arákùnrin Rẹ? January 15-21 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 6-7 Máa Wá Ìjọba Náà Lákọ̀ọ́kọ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ Dẹ́kun Ṣíṣàníyàn January 22-28 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 8-9 Jésù Fẹ́ràn Àwọn Èèyàn January 29–February 4 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 10-11 Jésù Mú Kí Ara Tù Wá