ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 January ojú ìwé 5
  • Ẹ Dẹ́kun Ṣíṣàníyàn

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ Dẹ́kun Ṣíṣàníyàn
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
  • Ẹ “Jẹ́ Kí Àwọn Nǹkan Tó Wà Báyìí Tẹ́ Yín Lọ́rùn”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • O Lè Sin Jèhófà Táwọn Òbí Ẹ Ò Bá Tiẹ̀ Ṣe Bẹ́ẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Sáwọn Míì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 January ojú ìwé 5

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ẹ Dẹ́kun Ṣíṣàníyàn

Ẹyẹ; òdòdó

Nínú Ìwàásù Orí Òkè, Jésù sọ pé: “Ẹ dẹ́kun ṣíṣàníyàn nípa ọkàn yín.” (Mt 6:25) Bó tilẹ̀ jẹ́ pé, kò sí bí àwa èèyàn aláìpé tí à ń gbé nínú ayé Sátánì yìí ò ṣe ní máa ṣàníyàn, síbẹ̀ ohun tí Jésù ń kọ́ àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ ni pé kí wọ́n yẹra fún àníyàn àṣejù. (Sm 13:2) Kí nìdí? Ìdí ni pé tí èèyàn bá ń ṣe àníyàn nípa àwọn nǹkan tó nílò, onítọ̀hún ò ní lè pọkàn pọ̀, á sì nira fún un láti wá Ìjọba náà lákọ̀ọ́kọ́. (Mt 6:33) Àwọn ohun tí Jésù tún sọ máa ràn wá lọ́wọ́ láti dẹ́kun ṣíṣe àníyàn tí kò pọn dandan.

  • Mt 6:26​—Kí la lè rí kọ́ tá a bá ń kíyè sí àwọn ẹyẹ? (w16.07 9-10 ¶11-13)

  • Mt 6:27​—Kí nìdí tá a fi lè sọ pé àníyàn àṣejù máa ń fi àkókò àti okun ẹni ṣòfò? (w05 11/1 22 ¶5)

  • Mt 6:​28-30​—Kí la lè rí kọ́ lára àwọn òdòdó lílì pápá? (w16.07 10-11 ¶15-16)

  • Mt 6:​31, 32​—Àwọn ọ̀nà wo ni àwa Kristẹni fi yàtọ̀ sí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè tí kò nígbàgbọ́? (w16.07 11 ¶17)

Àwọn nǹkan wo ni mi ò fẹ́ máa ṣàníyàn nípa rẹ̀?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́