ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 January ojú ìwé 6
  • Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Sáwọn Míì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Sáwọn Míì
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn sí Ara Yín
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • “Ibi Tí O Bá Lọ Ni Èmi Yóò Lọ”
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
  • “Ibi Tí O Bá Lọ Ni Èmi Yóò Lọ”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Rúùtù àti Náómì
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 January ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Sáwọn Míì

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Rúùtù.]

Náómì sọ fún Rúùtù àti Ọ́pà pé kí wọ́n pa dà sí ilẹ̀ Móábù (Rut 1:8-13; w16.02 10 ¶5)

Rúùtù sọ pé òun ò ní fi Náómì àti Jèhófà sílẹ̀ (Rut 1:16, 17; w16.02 10 ¶6)

Àwòrán: 1. Ìyá kan àtọmọbìnrin ẹ̀ ń bá tọkọtaya kan sọ̀rọ̀ lórí Kọ̀ǹpútà. 2. Tọkọtaya náà ń gbé oúnjẹ lọ fún ìyá yẹn àtọmọ ẹ̀.

Ẹni tó bá ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ máa ń jẹ́ olóòótọ́, ẹni tó ṣeé fọkàn tán, adúróṣinṣin àti ẹni tó máa ń dúró tini nígbà ìṣòro. Jèhófà máa ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ olóòótọ́. (Sm 63:3) Ó yẹ káwa náà máa fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sáwọn míì.​—Owe 21:21.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́