ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 May ojú ìwé 8
  • O Lè Sin Jèhófà Táwọn Òbí Ẹ Ò Bá Tiẹ̀ Ṣe Bẹ́ẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • O Lè Sin Jèhófà Táwọn Òbí Ẹ Ò Bá Tiẹ̀ Ṣe Bẹ́ẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Sáwọn Míì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ó Fún Wa Lómìnira Láti Ṣe Ohun Tó Wù Wá
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • ‘Ó Ń Bá A Nìṣó Ní Fífà Mọ́ Jèhófà’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Àwòkọ́ṣe—Hesekáyà
    Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 May ojú ìwé 8

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

O Lè Sin Jèhófà Táwọn Òbí Ẹ Ò Bá Tiẹ̀ Ṣe Bẹ́ẹ̀

Ọba Áhásì bàbá Hẹsikáyà ṣe ohun tó burú gan-an lojú Jèhófà (2Kr 28:1; w16.02 10 ¶8)

Hẹsikáyà pinnu láti sin Jèhófà bó tiẹ̀ jẹ́ pé bàbá ẹ̀ jẹ́ abọ̀rìṣà (2Kr 29:1-3; w16.02 11 ¶9-11)

Hẹsikáyà fún àwọn míì níṣìírí pé kí wọ́n má ṣíwọ́ láti máa sin Jèhófà, bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn bàbá wọn ò sin Jèhófà (2Kr 29:4-6)

Àwòrán: 1. Ọ̀dọ́kùnrin kan ń múra ìpàdé sílẹ̀ bí àwọn ìdílé ẹ̀ tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ń múra sílẹ̀ fún ayẹyẹ kan. 2. Ọ̀dọ́kùnrin yìí ń dáhùn nípàdé.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn nǹkan wo ni mo lè ṣe tó máa fún àwọn ọ̀dọ́ táwọn òbí wọn ò sin Jèhófà níṣìírí láti máa sin Jèhófà nìṣó?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́