ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 May ojú ìwé 6
  • Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ǹjẹ́ Ìyà Tó Ń Jẹ Wá Tiẹ̀ Kan Ọlọ́run?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2018-2019—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • ‘Máa Sọ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Láìṣojo’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • Kí Nìdí Tí Ọlọ́run fi Fàyè Gba Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 May ojú ìwé 6
Ọmọbìnrin Ísírẹ́lì kan ń bá ìyàwó Náámánì sọ̀rọ̀

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà

Tó o bá ṣì wà ní iléèwé, ṣé ẹ̀rù máa ń bà ẹ́ láti jẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ pé Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni ẹ́, tó sì máa ń ṣòro fún ẹ láti wàásù? Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, báwo lo ṣe lè “máyàle” kó o lè máa fi ìgboyà sọ̀rọ̀ Ọlọ́run? (1Tẹ 2:2) Kí nìdí tó fi yẹ kó o ṣe bẹ́ẹ̀? Wo fídíò náà Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà, lẹ́yìn náà, kó o wá dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:

  1. Tósìn ń fún Ṣèyí ní ìwé Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Olùkọ́ Ńlá Náà; ọmọkùnrin kan tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí ń ka ìwé Awọn Ìbéèrè Tí Awọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè fún ọmọ iléèwé rẹ̀ kan

    Àpẹẹrẹ wo nínú Bíbélì ló mú kí Tósìn nígboyà?

  2. Báwo ni ìdánrawò ṣe ran Tósìn lọ́wọ́?

  3. Kí nìdí tó fi yẹ kó o máa wàásù fáwọn ọmọ iléèwé rẹ?

  4. Ẹ̀kọ́ wo làwọn tó ti kúrò níléèwé lè rí kọ́ látinú fídíò yìí?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́