May Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, May 2018 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ May 7-13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 7-8 Gbé Òpó Igi Oró Rẹ, Kí Ó sì Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Tẹ̀ Lé Kristi May 14-20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 9-10 Ìran Tó Ń Fún Ìgbàgbọ́ Lókun MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Ohun Tí Ọlọ́rùn Ti So Pọ̀ . . . ” May 21-27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 11-12 Ó Fi Púpọ̀ Sí I Ju Àwọn Tó Kù Lọ May 28–June 3 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 13-14 Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìbẹ̀rù Èèyàn Dẹkùn Mú Ẹ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà