ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 May ojú ìwé 3
  • Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Tẹ̀ Lé Kristi

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Tẹ̀ Lé Kristi
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ̀yin Òbí, Ṣé Ẹ̀ Ń Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣèrìbọmi?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • Ṣó Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Ṣe Ìrìbọmi?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Àfikún
    A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà
  • Ìrìbọmi Ṣe Pàtàkì!
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 May ojú ìwé 3
Ọmọkùnrin kan ṣe ìrìbọmi

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Tẹ̀ Lé Kristi

Ohun tó ń fún àwọn òbí tó jẹ́ Kristẹni láyọ̀ tó ga jù ni bí wọ́n ṣe ń rí i pé ọmọ wọn ‘sẹ́ níní ara rẹ̀, ó gbé òpó igi oró rẹ̀, ó sì ń tọ’ Jésù lẹ́yìn. (Mk 8:34; 3Jo 4) Kí làwọn òbí lè ṣe láti ran àwọn ọmọ wọn lọ́wọ́ kí wọ́n lè máa tẹ̀ lé Jésù, kí wọ́n ya ara wọn sí mímọ́ fún Jèhófà, kí wọ́n sì ṣe ìrìbọmi? Kí làwọn ọmọ yín ń ṣe tó fi hàn pé wọ́n ti ṣe tán láti ṣe ìrìbọmi?

A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà

Ka “Ọ̀rọ̀ Ìyànjú fún Àwọn Òbí” ní ojú ìwé 165 àti 166 nínú ìwé A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà, kó o sì ronú lórí àwọn ìbéèrè yìí:

  1. Kí ló túmọ̀ sí láti jẹ́ ọmọ ẹ̀yìn?

  2. Kí ló yẹ kí àwọn òbí kọ́ àwọn ọmọ wọn?

  3. Ní ìbámu pẹ̀lú ọjọ́ orí wọn, báwo ló ṣe yẹ kí àwọn ọmọ fi àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí sílò kí wọ́n lè tóótun láti ṣe ìrìbọmi?

    • Kol 3:20

    • Lk 2:46

    • Sm 122:1

    • Mt 4:4

    • Mt 6:33

    • 1Kọ 15:33

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́