Pọ́ọ̀lù àti Bánábà níwájú Sájíọ́sì Pọ́lọ́sì
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 12-14
Bánábà àti Pọ́ọ̀lù Sọ Àwọn Èèyàn Tó Wà Láwọn Ọ̀nà Jíjìn Di Ọmọlẹ́yìn
Àwọn èèyàn ta ko Bánábà àti Pọ́ọ̀lù, síbẹ̀ àwọn méjèèjì ṣiṣẹ́ kára káwọn ọlọ́kàn tútù lè di Kristẹni
Wọ́n wàásù fún àwọn èèyàn láìka ibi tí wọ́n ti wá sí
Wọ́n gbóríyìn fún àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ di ọmọlẹ́yìn pé kí wọ́n “dúró nínú ìgbàgbọ́”