ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 1-3 Máa Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ 2:14, 15 Ẹ̀rí ọkàn wa máa ṣiṣẹ́ dáadáa tá a bá fi àwọn ìlànà Bíbélì kọ́ ọ tẹ́tí sí i nígbà tó bá rán wa létí àwọn ìlànà yẹn gbàdúrà pé kí ẹ̀mí mímọ́ ràn wá lọ́wọ́ láti máa ṣe ohun tó tọ́.—Ro 9:1