ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 February ojú ìwé 6
  • Àpèjúwe Igi Ólífì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àpèjúwe Igi Ólífì
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ‘Ìjìnlẹ̀ Ọgbọ́n Ọlọ́run Mà Pọ̀ O!’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Igi Ólífì Gbígbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ Nínú Ilé Ọlọ́run
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • Ní Ìgbàgbọ́ Tó Fẹsẹ̀ Múlẹ̀ Ṣinṣin Nínú Ìjọba Ọlọ́run
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
  • Jóòbù Gbà Pé Àjíǹde Máa Wà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 February ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 9-11

Àpèjúwe Igi Ólífì

11:16-26

Kí ni apá ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lára igi náà dúró fún?

Igi ólífì tí Bíbélì mẹ́nu kàn nínú Róòmù orí kọkànlá
  • Igi náà: dúró fún bí májẹ̀mú tí Ọlọ́run bá Ábúráhámù dá ṣe ní ìmúṣẹ

  • Ìtì igi náà: dúró fún Jésù tó jẹ́ apá àkọ́kọ́ lára irú ọmọ Ábúráhámù

  • Àwọn ẹ̀ka: dúró fún apá kejì lára irú ọmọ Ábúráhámù

  • Àwọn ẹ̀ka tá a ṣẹ́ kúrò: dúró fún àwọn Júù nípa tara tí wọ́n kọ Jésù sílẹ̀

  • Àwọn ẹ̀ka tá a lọ́ mọ́ ọn: dúró fún àwọn Kristẹni tá a fẹ̀mí yàn lára àwọn orílẹ̀-èdè

Bí Bíbélì ṣe sọ tẹ́lẹ̀, irú ọmọ Ábúráhámù, ìyẹn Jésù àti ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì (144,000) máa mú ìbùkún wá fún “àwọn ènìyàn orílẹ̀-èdè.”​—Ro 11:12; Jẹ 22:18

Kí ni mo kọ́ lára Jèhófà nínú ọ̀nà tó gbà mú ìlérí tó ṣe nípa irú ọmọ Ábúráhámù ṣẹ?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́