ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 March ojú ìwé 4
  • Ṣé Ẹni Tara Ni Ẹ́ Tàbí Ẹni Tẹ̀mí?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ẹni Tara Ni Ẹ́ Tàbí Ẹni Tẹ̀mí?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Ló Túmọ̀ Sí Láti Sún Mọ́ Ọlọ́run? Ṣé Mo Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run Bí Mi Ò Bá Ṣe Ẹ̀sìn Kankan?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Onírúurú Èrò Nípa Béèyàn Ṣe Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Sapá Láti Túbọ̀ Di Ẹni Tẹ̀mí
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • Awọn Ìdílé Kristian Ń fi Àwọn Ohun Tẹ̀mí Sí Ipò Àkọ́kọ́
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 March ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 KỌ́RÍŃTÌ 1-3

Ṣé Ẹni Tara Ni Ẹ́ Tàbí Ẹni Tẹ̀mí?

2:14-16

Ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ló yẹ kó máa sapá láti di ẹni tẹ̀mí, kó sì máa tẹ̀ síwájú. (Ef 4:23, 24) Kó o tó lè máa tẹ̀ síwájú, o gbọ́dọ̀ máa jẹ oúnjẹ tẹ̀mí déédéé, kó o ní àwọn àfojúsùn tẹ̀mí, kó o sì máa fi àwọn èso tẹ̀mí ṣèwà hù.

Eré ìdárayá, àwọn àfojúsùn àti ọ̀rọ̀ tí ẹni tara àti ẹni tẹ̀mí á máa sọ

Báwo ni ipò tẹ̀mí rẹ ṣe rí báyìí tó o bá fi wéra pẹ̀lú bó ṣe rí lọ́dún tó kọjá, ọdún mẹ́wàá sẹ́yìn tàbí nígbà tó o ṣèrìbọmi?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́