March Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé March 2019 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ March 4-10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 12-14 Ohun Tó Túmọ̀ Sí Láti Fi Ìfẹ́ Hàn Síra Wa March 11-17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 15-16 Bẹ Jèhófà Pé Kó Fún Ẹ Ní Ìfaradà Kó sì Tù Ẹ́ Nínú March 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 KỌ́RÍŃTÌ 1-3 Ṣé Ẹni Tara Ni Ẹ́ Tàbí Ẹni Tẹ̀mí? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bó O Ṣe Lè Kọ Lẹ́tà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àpẹẹrẹ Lẹ́tà Tá A Lè Fi Wàásù March 25-31 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 KỌ́RÍŃTÌ 4-6 “Ìwúkàrà Díẹ̀ Ní Í Mú Gbogbo Ìṣùpọ̀ Di Wíwú” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Fi Fídíò Kọ́ Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì