ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 March ojú ìwé 2
  • March 4-10

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 4-10
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 March ojú ìwé 2

March 4-10

RÓÒMÙ 12-14

  • Orin 106 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ohun Tó Túmọ̀ Sí Láti Fi Ìfẹ́ Hàn Síra Wa”: (10 min.)

    • Ro 12:10​—Ká ní ìfẹ́ni fáwọn ará wa (it-1 55)

    • Ro 12:17-19​—Tẹ́nì kan bá ṣẹ̀ wá, ká má gbẹ̀san (w09 10/15 8 ¶3; w07 7/1 24-25 ¶12-13)

    • Ro 12:20, 21​—Fi ire ṣẹ́gun ibi (w12 11/15 29 ¶13)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ro 12:1​—Kí ni ẹsẹ yìí túmọ̀ sí? (lv 64 ¶5-6)

    • Ro 13:1​—Ọ̀nà wo ni a gbà gbé àwọn aláṣẹ onípò gíga “dúró sí àwọn ipò wọn aláàlà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run”? (w08 6/15 31 ¶4)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 13:1-14 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Lo Ìbéèrè Bó Ṣe Yẹ, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 3 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.

  • Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w11 9/1 21-22​—Àkòrí: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Káwa Kristẹni Máa San Owó Orí Tí Wọn Bá Tiẹ̀ Ń Fi Owó Yẹn Ṣe Àwọn Nǹkan Tí Kò Tọ́? (th ẹ̀kọ́ 3)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 77

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 3 ¶13-20

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 57 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́