ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 March ojú ìwé 2
  • Ohun Tó Túmọ̀ Sí Láti Fi Ìfẹ́ Hàn Síra Wa

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó Túmọ̀ Sí Láti Fi Ìfẹ́ Hàn Síra Wa
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìfẹ́ Ọlọ́run Tó Dúró Ṣinṣin
    Kọrin sí Jèhófà
  • Ìfẹ́ Ọlọ́run tí Kì Í Yẹ̀
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • “Ẹ Má Ṣe Fi Ibi San Ibi Fún Ẹnì Kankan”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 March ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 12-14

Ohun Tó Túmọ̀ Sí Láti Fi Ìfẹ́ Hàn Síra Wa

12:10, 17-21

Tẹ́nì kan bá ṣàìdáa sí wa, yàtọ̀ sí pé kò yẹ ká ṣàìdáa sẹ́ni náà pa dà, ohun tó túmọ̀ sí láti fi ìfẹ́ hàn ni pé ká ṣoore fẹ́ni yẹn pa dà. “Bí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ, fún un ní oúnjẹ jẹ; bí òùngbẹ bá ń gbẹ ẹ́, fún un ní ohun kan láti mu; nítorí nípa ṣíṣe èyí, ìwọ yóò máa kó òkìtì ẹyín iná lé e ní orí.” (Ro 12:20) Oore tá a bá ṣe sẹ́ni tó ṣàìdáa sí wa tiẹ̀ lè mú kẹ́ni náà kábàámọ̀ ohun tó ṣe.

Ẹnì kan sọ̀rọ̀ kòbákùngbé sí arábìnrin yìí níbi iṣẹ́, ó sọ fún alàgbà kan lálẹ́ ọjọ́ yẹn, lọ́jọ́ kejì ó hùwà dáadáa sí ẹni yẹn níbi iṣẹ́

Báwo ló ṣe rí lára rẹ nígbà tẹ́ni tó o ṣẹ̀ láìmọ̀ọ́mọ̀ fàánú hàn sí ẹ pa dà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́