ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 April ojú ìwé 6
  • Ọlọ́run Máa Di “Ohun Gbogbo fún Kálukú”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọlọ́run Máa Di “Ohun Gbogbo fún Kálukú”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Gbogbo Ìgbà Ni Jèhófà Máa Ń Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Kóo Máa Mú Ìlérí Rẹ Ṣẹ?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
  • Àlàáfíà Yóò Wà Fún Ẹgbẹ̀rún Ọdún Àti Títí Láé!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • “Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 April ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 KỌ́RÍŃTÌ 14-16

Ọlọ́run Máa Di “Ohun Gbogbo fún Kálukú”

15:​24-28

Ọjọ́ ọ̀la ológo ló ń dúró de àwọn tó bá jẹ́ olóòótọ́ sí Jèhófà. Àwọn ìlérí Jèhófà máa túbọ̀ jinlẹ̀ lọ́kàn wa tá a bá ń fi ìtara sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ fún àwọn míì. Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ fún àwọn ará pé kí wọ́n ronú lórí bí nǹkan ṣe máa rí ní òpin Ẹgbẹ̀rún Ọdún Ìṣàkóso Kristi, nígbà tí Jèhófà máa di “ohun gbogbo fún kálukú.”

Àwọn áńgẹ́lì ń dáàbò bo àwọn èèyàn Jèhófà nígbà ìpọ́njú ńlá; àwọn èèyàn nínú Párádísè; Jésù yọ adé lórí, ó sì gbé Ìjọba fún Jèhófà Ọlọ́run

Èwo nínú àwọn ìlérí tá à ń retí yìí ló wọ̀ ẹ́ lọ́kàn jù lọ, kí sì nìdí?

Kí ló jẹ́ kó dá ẹ lójú pé Ọlọ́run máa ṣe àwọn nǹkan tó ṣèlérí?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́