ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 April ojú ìwé 7
  • Jèhófà​—“Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà​—“Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìrẹ̀lẹ́kún Láti Ọ̀dọ̀ “Ọlọrun Ìtùnú Gbogbo”
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
  • ‘Ẹ Máa Sunkún Pẹ̀lú Àwọn Tí Ń Sunkún’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, “Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 April ojú ìwé 7
Àwọn ọkùnrin méjì tó wà nínú ilé ìwòsàn yìí banú jẹ́ gan-an

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 KỌ́RÍŃTÌ 1-3

Jèhófà​—“Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo”

1:3, 4

Ìjọ Kristẹni jẹ́ ọ̀nà kan tí Jèhófà gbà ń tù wá nínú. Kí làwọn nǹkan tá a lè ṣe láti tu àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ nínú?

  • Tẹ́tí sí wọn, má dá ọ̀rọ̀ mọ́ wọn lẹ́nu

  • “Ẹ máa sunkún pẹ̀lú àwọn tó ń sunkún.”​—Ro 12:15

  • O lè kọ ọ̀rọ̀ tó ń gbéni ró sínú káàdì, kó o sì fún wọn, o sì lè fi ọ̀rọ̀ ránṣẹ́ sí wọn lórí fóònù tàbí kọ̀ǹpútà.​—w17.07 15, àpótí

  • Gbàdúrà fún wọn, kó o sì gbàdúrà pẹ̀lú wọn

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló ti rí ìtùnú nínú àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí:

  • “Jèhófà wà nítòsí àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn; ó ń gba àwọn tí àárẹ̀ bá ẹ̀mí wọn là.”​—Sm 34:​18, 19

  • “Nígbà tí àníyàn bò mí mọ́lẹ̀, o tù mí nínú, o sì tù mí lára.”​—Sm 94:19

  • “Kí Olúwa wa Jésù Kristi fúnra rẹ̀ àti Ọlọ́run, Baba wa, ẹni tó nífẹ̀ẹ́ wa, tó sì fún wa ní ìtùnú ayérayé àti ìrètí rere nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí, tu ọkàn yín lára, kó sì fìdí yín múlẹ̀ gbọn-in.”​—2Tẹ 2:​16, 17

Ẹnì kan ń kọ ẹsẹ ìwé mímọ́ tó máa tuni nínú sínú káàdì
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́