ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 August ojú ìwé 2
  • “Ọlọ́run Kò Fún Wa Ní Ẹ̀mí Ojo”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ọlọ́run Kò Fún Wa Ní Ẹ̀mí Ojo”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • 2 Tímótì 1:7—“Ọlọ́run Kò Fún Wa Ní Ẹ̀mí Ìbẹ̀rù”
    Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì
  • Tímótì—“Ojúlówó Ọmọ Nínú Ìgbàgbọ́”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
  • Kí Ló Lè Ràn Wá Lọ́wọ́ Láti Fi Ọwọ́ Títọ̀nà Mú Òtítọ́?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • ‘Ẹ Jẹ́ Onígboyà Àti Alágbára!’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 August ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 TÍMÓTÌ 1-4

“Ọlọ́run Kò Fún Wa Ní Ẹ̀mí Ojo”

1:7, 8

Tímótì ń ka àkájọ ìwé tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù kọ

Ọ̀rọ̀ onímìísí tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ fún Tímótì fún wa níṣìírí gan-an. Dípò ká máa tijú ìhìn rere, ó yẹ ká fìgboyà sọ̀rọ̀ láti gbèjà ìgbàgbọ́ wa, kódà tó bá tiẹ̀ gba pé ká “jìyà.”

Àwọn ìgbà wo ló máa gba pé kí n lo ìgboyà?

Ọ̀dọ́bìnrin Ẹlẹ́rìí kan ń fi ìwé pẹlẹbẹ Origin of Life han àwọn ọmọ kíláàsì àti olùkọ́ rẹ̀; arábìnrin kan ò gbà lati ṣe igi Kérésìmesì lọ́ṣọ̀ọ́ níbiṣẹ́; arákùnrin kan ń wàásù níbiṣẹ́
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́