ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 August ojú ìwé 7
  • Sa Gbogbo Ipá Rẹ Kó O Lè Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Sa Gbogbo Ipá Rẹ Kó O Lè Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Ni Ìsinmi Ọlọ́run?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2001
  • Ṣé O Ti Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • O Ha Ti Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run Bí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1998
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 August ojú ìwé 7
Ọkọ àtìyàwó kan ń wo bí oòrùn ṣe ń wọ̀, àwọn mí ì ń gbádùn oúnjẹ pa pọ̀ nínú párádísè

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÉBÉRÙ 4-6

Sa Gbogbo Ipá Rẹ Kó O Lè Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run

4:11

A lè wọnú ìsinmi Jèhófà tá a bá jẹ́ onígbọràn tá a sì ń tẹ̀ lé àwọn ìtọ́ni tó ń fún wa nípasẹ̀ ètò rẹ̀. Ó yẹ ká bi ara wa pé: ‘Tí wọ́n bá fún mi nímọ̀ràn, irú ọwọ́ wo ni mo máa ń fi mú un? Tí wọ́n bá ṣàtúnṣe sí òye tá a ní nípa Bíbélì, kí ni mo máa ń ṣe?’

Kí làwọn nǹkan tó máa ń ṣẹlẹ̀ sí mi, tó máa ń dán mi wò bóyá lóòótọ́ ni mo jẹ́ onígbọràn?

Arákùnrin méjì ń fi Bíbélì gba arábìnrin kan nímọ̀ràn; arákùnrin kan ń ṣe ìdákẹ́kọ̀ọ́, ó sì ń ṣàyẹ̀wo àwọn àtúnṣe tó wà lórí òye tá a ní nípa àwọn ẹ̀kọ́ Bíbélì kan
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́