ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 November ojú ìwé 5
  • “Mo Mọ Àwọn Iṣẹ́ Rẹ”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Mo Mọ Àwọn Iṣẹ́ Rẹ”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • A Rí Ìtumọ̀ Àṣírí Ọlọ́wọ̀ Kan
    Ìṣípayá—Ìparí Rẹ̀ Ológo Kù sí Dẹ̀dẹ̀!
  • Kristi Ni Aṣáájú Ìjọ Rẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
  • Bá A Ṣe Ṣètò Ìjọ Kristẹni
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Jòhánù Rí Jésù Tí Ọlọ́run Ti Ṣe Lógo
    Ìṣípayá—Ìparí Rẹ̀ Ológo Kù sí Dẹ̀dẹ̀!
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 November ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 1-3

“Mo Mọ Àwọn Iṣẹ́ Rẹ”

1:20; 2:1, 2

  • Àwọn alàgbà méjì ń bá arákùnrin kan sọ̀rọ̀; Jésù kó àwọn ìràwọ̀ méje náà dání

    “Ìràwọ̀ méje”: Ó tọ́ka sí àwọn alàgbà tó jẹ́ ẹni àmì òróró, àmọ́ ó tún kan gbogbo àwọn alàgbà lápapọ̀

  • “Ní ọwọ́ ọ̀tún [Jésù]”: Ìkáwọ́ Jésù làwọn ìràwọ̀ yìí wà, òun ló ń darí wọn, òun ló sì ń tọ́ wọn sọ́nà. Tí ẹnì kan nínú ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà bá nílò ìbáwí, Jésù máa bá a wí bó ṣe yẹ àti nígbà tó yẹ

  • “Ọ̀pá fìtílà méje tí wọ́n fi wúrà ṣe”: Ìjọ Kristẹni. Bí ọ̀pá fìtílà tó wà nínú àgọ́ ìjọsìn ṣe ń tànmọ́lẹ̀ sínú àgọ́ náà, bẹ́ẹ̀ ni ìjọ Kristẹni ń tànmọ́lẹ̀ nínú ayé. (Mt 5:14) Jésù “ń rìn láàárín” àwọn ọ̀pá fìtílà náà ní ti pé ó ń darí ohun tó ń lọ nínú gbogbo ìjọ

Báwo ni ìran yìí ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ . . .

  • Nígbà táwọn alàgbà bá tọ́ ẹ sọ́nà tàbí tí wọ́n bá ẹ wí?

  • Tó bá dà bíi pé nǹkan ò lọ bó ṣe yẹ nínú ìjọ?

  • Láti máa fìtara wàásù nígbà gbogbo?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́