ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 October ojú ìwé 4
  • Àwọn Ànímọ́ Jèhófà Tó Fani Mọ́ra

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ànímọ́ Jèhófà Tó Fani Mọ́ra
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Ṣàpèjúwe Irú Ẹni Tóun Jẹ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Báwo Ni Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì Í Yẹ̀ Ṣe Ń Ṣe Ọ́ Láǹfààní?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • Ìfẹ́ Kì Í Yẹ̀
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Mọ Àwọn Ọ̀nà Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 October ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 33-34

Àwọn Ànímọ́ Jèhófà Tó Fani Mọ́ra

34:​5-7

Mósè mọyì àwọn ànímọ́ Jèhófà, ìdí nìyẹn tó fi ń fi sùúrù bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lò. Táwa náà bá mọyì àwọn ànímọ́ Jèhófà, àá máa ṣàánú àwọn ará wa.

  • “Ọlọ́run aláàánú, tó ń gba tẹni rò”: Báwọn òbí ṣe máa ń tọ́jú àwọn ọmọ wọn, bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà ṣe máa ń fìfẹ́ bójú tó àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, tó sì ń gba tiwọn rò

  • “Kì í tètè bínú”: Jèhófà máa ń mú sùúrù fáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ kí wọ́n lè ṣàtúnṣe sí ìwà wọn

  • “Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ . . . pọ̀ gidigidi”: Bí Jèhófà ṣe ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ mú kí wọ́n ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú rẹ̀

Àwòrán: Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jèhófà. 1. Alàgbà méjì lọ ṣèbẹ̀wò sọ́dọ̀ ìdílé kan, wọ́n ka Bíbélì láti fún wọn níṣìírí. 2. Arábìnrin kan ń tu arábìnrin tó ń sunkún nínú.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn ọ̀nà wo ni mo lè gbà máa fi àánú hàn bíi ti Jèhófà?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́