ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 11
  • Jẹ́ Oníwà Pẹ̀lẹ́ Kódà Nígbà Tí Kò Bá Rọrùn

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jẹ́ Oníwà Pẹ̀lẹ́ Kódà Nígbà Tí Kò Bá Rọrùn
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Bá Ò Ṣe Ní Pàdánù Ojúure Ọlọ́run Bí Ìyípadà Bá Tiẹ̀ Dé Bá Wa
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • Jẹ́ Ọlọ́kàn Tútù Kó O Lè Múnú Jèhófà Dùn
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Máa Fi Hàn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 11
Arákùnrin kan ń múra láti lọ sípàdé. Ó dákẹ́ nígbà tí bàbá rẹ̀ tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń jágbe mọ́ ọn. Wọ́n fi igi Kérésìmesì àtàwọn ère ìjọsìn lóríṣiríṣi ṣe ilé náà lọ́ṣọ̀ọ́.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jẹ́ Oníwà Pẹ̀lẹ́ Kódà Nígbà Tí Kò Bá Rọrùn

Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Mósè nínú aginjù mú kó nira fún un láti jẹ́ oníwà pẹ̀lẹ́ (Nọ 20:​2-5; w19.02 12 ¶19)

Láàárín àkókò kan, Mósè ṣe ohun tó fi hàn pé kò ní ìwà pẹ̀lẹ́ (Nọ 20:10; w19.02 13 ¶20-21)

Jèhófà bá Mósè àti Áárónì wí torí àṣìṣe ńlá tí wọ́n ṣe (Nọ 20:12; w09 9/1 19 ¶5)

Ẹni tó ní ìwà pẹ̀lẹ́ kì í tètè bínú, kì í gbéra ga, kì í sì í mọ tara ẹ̀ nìkan. Táwọn èèyàn bá tiẹ̀ múnú bí i, ó máa ń ní sùúrù, kì í gbaná jẹ, kì í sì í fi ibi san ibi.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́