ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 11
  • Máa Ka Bíbélì Lójoojúmọ́ Kó O Lè Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Ka Bíbélì Lójoojúmọ́ Kó O Lè Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Máa Ṣàkọsílẹ̀ Ìtẹ̀síwájú Rẹ
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O sì Gbà Pé Àwọn Nǹkan Kan Wà Tó Ò Mọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
  • Bí Iṣẹ́ Ìwàásù Ṣe Lè Túbọ̀ Máa Fún Ẹ Láyọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2024
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 11

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Máa Ka Bíbélì Lójoojúmọ́ Kó O Lè Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n

Ọgbọ́n tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ṣeyebíye bí ìṣúra tó fara sin. (Owe 2:1-6) Ọgbọ́n máa ń jẹ́ ká lè fòye mọ nǹkan ká sì ṣe ìpinnu tó dáa, ó tún máa ń dáàbò bò wá. Torí náà, ọgbọ́n ni “ohun tó ṣe pàtàkì jù lọ.” (Owe 4:5-7) Ó gba ìsapá ká tó lè rí àwọn ìṣúra tó fara sin tó wà nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. Ó máa gba pé ká máa ka Bíbélì “tọ̀sántòru” ìyẹn lójoojúmọ́. (Joṣ 1:8) Wo àwọn àbá tó lè ràn wá lọ́wọ́ ká lè máa ka Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run déédéé ká sì máa gbádùn ẹ̀.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ ÀWỌN Ọ̀DỌ́ TÓ KỌ́ BÍ WỌ́N ṢE LÈ NÍFẸ̀Ẹ́ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

Kí ló jẹ́ kó ṣòro fáwọn ọ̀dọ́ yìí láti máa ka Bíbélì lójoojúmọ́, kí ló sì ràn wọ́n lọ́wọ́?

  • Apá kan nínú fídíò “Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Kọ́ Bí Wọ́n Ṣe Lè Nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.” Melanie.

    Melanie

  • Apá kan nínú fídíò “Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Kọ́ Bí Wọ́n Ṣe Lè Nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.” Samuel.

    Samuel

  • Apá kan nínú fídíò “Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Kọ́ Bí Wọ́n Ṣe Lè Nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.” Celine.

    Celine

  • Apá kan nínú fídíò “Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Kọ́ Bí Wọ́n Ṣe Lè Nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.” Raphaello.

    Raphaello

ÌTÒLẸ́SẸẸSẸ BÍBÉLÌ KÍKÀ MI:

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́