ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 15
  • Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Ka Bíbélì Lójoojúmọ́ Kó O Lè Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Máa Ṣàkọsílẹ̀ Ìtẹ̀síwájú Rẹ
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Máa Ṣe Ìpinnu Táá Múnú Jèhófà Dùn
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O sì Gbà Pé Àwọn Nǹkan Kan Wà Tó Ò Mọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 15

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà

Ojoojúmọ́ la máa ń bára wa láwọn ipò tó gba pé ká ṣèpinnu. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló jẹ́ pé bí nǹkan bá ṣe rí lára wọn tàbí ohun tí ọ̀pọ̀ èèyàn ń ṣe ni wọ́n máa ń gbé àwọn ìpinnu wọn ka. (Ẹk 23:2; Owe 28:26) Àmọ́ àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà “máa kíyè sí i” ní ti pé wọ́n máa ń lo àwọn ìlànà Bíbélì tí wọ́n bá fẹ́ ṣèpinnu.​—Owe 3:5, 6.

Kọ àwọn ipò tí àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí ti lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti ṣe àwọn ìpinnu tó dáa.

  • Mt 6:33

  • Ro 12:18

  • 1Kọ 10:24

  • Ef 5:15, 16

  • 1Ti 2:9, 10

  • Heb 13:5

JẸ́ KÍ ÀWỌN ARÁ WO FÍDÍÒ TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÀWỌN TÓ NÍ ÌGBÀGBỌ́, KÌ Í ṢE ÀWỌN TÍ KÒ NÍGBÀGBỌ́—TẸ̀ LÉ MÓSÈ, MÁ TẸ̀ LÉ FÁRÁÒ, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÌBÉÈRÈ TÓ TẸ̀ LÉ E YÌÍ:

Apá kan nínú fídíò “Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Tó Ní Ìgbàgbọ́, Kì Í Ṣe Àwọn Tí Kò Nígbàgbọ́​—Tẹ̀ Lé Mósè, Má Tẹ̀ Lé Fáráò.” Arákùnrin kan tó ń lọ sí àpéjọ agbègbè gba ìpè pàjáwìrì láti ibiṣẹ́.

Báwo ni àpẹẹrẹ kan nínú Bíbélì ṣe ran arákùnrin yìí lọ́wọ́ láti ṣe ìpinnu tó tọ́?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́