ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 14
  • Ìgbà Wo Ló Yẹ Ká Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìgbà Wo Ló Yẹ Ká Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • “Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jèhófà Ọlọ́run Yín”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • “Ẹ̀san Wà fún Ìgbòkègbodò Yín”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n ní Àkókò Àlàáfíà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2020
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 14

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ìgbà Wo Ló Yẹ Ká Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà?

Ásà gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà nígbà táwọn ọmọ ogun tó pọ̀ gan-an dojú kọ ọ́, ìyẹn sì jẹ́ kó ṣẹ́gun (2Kr 14:9-12; w21.03 5 ¶12)

Àmọ́ nígbà tó yá, Ásà wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ àwọn ará Síríà nígbà táwọn ọmọ ogun tí kò fi bẹ́ẹ̀ pọ̀ wá gbógun jà á (2Kr 16:1-3; w21.03 5 ¶13)

Inú Jèhófà ò dùn sí Ásà torí pé kò gbẹ́kẹ̀ lé e mọ́ (2Kr 16:7-9)

Àwòrán: 1. Ọ̀dọ́kùnrin kan ń ṣèrìbọmi. 2. Ọ̀dọ́kùnrin náà ń wo tẹlifíṣọ̀n, ó sì fẹ́ pinnu ètò tóun máa wò.

A máa gbára lé Jèhófà tá a bá fẹ́ ṣe àwọn ìpinnu tó ṣe pàtàkì. Àmọ́ tá a bá fẹ́ ṣe àwọn nǹkan tí kò fi bẹ́ẹ̀ ṣe pàtàkì ńkọ́? Ó yẹ ká máa gbára lé Jèhófà nínú gbogbo ohun tá a bá ń ṣe.​—Owe 3:5, 6; w21.03 6 ¶14.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́