ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 July ojú ìwé 8
  • Nehemáyà Fi Ara Ẹ̀ Jìn Dípò Kó Jẹ Gàba

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Nehemáyà Fi Ara Ẹ̀ Jìn Dípò Kó Jẹ Gàba
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Máa Fi Ire Ṣẹ́gun Ibi”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • “Jọ̀wọ́, Ọlọ́run Mi, Rántí Mi fún Rere”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Nehemáyà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Odi Jerúsálẹ́mù
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 July ojú ìwé 8
Nehemáyà fọwọ́ kún iṣẹ́ kíkọ́ ògiri Jerúsálẹ́mù.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Nehemáyà Fi Ara Ẹ̀ Jìn Dípò Kó Jẹ Gàba

Nehemáyà kò fi ipò ẹ̀ wá àǹfààní ara ẹ̀ (Ne 5:14, 15, 17, 18; w02 11/1 27 ¶3)

Nehemáyà ò káwọ́ gbera, kó sì máa pàṣẹ fáwọn èèyàn náà; dípò bẹ́ẹ̀ òun fúnra ẹ̀ lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ náà (Ne 5:16; w16.09 6 ¶16)

Nehemáyà bẹ Jèhófà pé kó rántí gbogbo ohun tí òun ṣe fáwọn èèyàn náà (Ne 5:19; w00 2/1 32)

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé gómìnà ni Nehemáyà, kò retí pé káwọn èèyàn máa gbé òun gẹ̀gẹ̀. Àpẹẹrẹ tó dáa nìyẹn jẹ́ fún gbogbo àwọn tó ní àǹfààní iṣẹ́ ìsìn nínú ìjọ.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé ohun tí mo lè ṣe fáwọn míì ló máa ń gbà mí lọ́kàn, àbí ohun táwọn míì lè ṣe fún mi?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́