ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Má Ṣe Pa Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Ń Sin Jèhófà Tì
Àwọn mọ̀lẹ́bí Jóòbù pa á tì (Job 19:13)
Àwọn ìránṣẹ́ Jóòbù àtàwọn ọmọdé ń fi ojú àbùkù wò ó (Job 19:16, 18)
Àwọn ọ̀rẹ́ Jóòbù tímọ́tímọ́ kẹ̀yìn sí i (Job 19:19)
BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo nífẹ̀ẹ́ àwọn tá a jọ ń sin Jèhófà tí wọ́n bá wà nínú ìṣòro?’—Owe 17:17; w22.01 16 ¶9; w21.09 30 ¶16; w90 9/1 22 ¶20.