ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mrt àpilẹ̀kọ 107
  • Jésù Máa Fòpin sí Ogun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jésù Máa Fòpin sí Ogun
  • Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jésù Máa Fòpin sí Ipò Òṣì
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Ta Ló Máa Gba Àwọn Aráàlú?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Kí Nìdí Tí Ọ̀rọ̀ Òṣèlú Fi Túbọ̀ Ń Mú Káwọn Èèyàn Kẹ̀yìn Síra?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Ìjọba Ọlọ́run—Kí Nìdí Tó fi Ṣe Pàtàkì Gan-an sí Jésù?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
Àwọn Míì
Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
mrt àpilẹ̀kọ 107
Àwọn ọ̀dọ́kùnrin méjì jókòó, wọ́n sì ń wo agbègbè tí ogun ti bà jẹ́.

AspctStyle/stock.adobe.com

Jésù Máa Fòpin sí Ogun

Jésù fi hàn pé òun nífẹ̀ẹ́ àwa èèyàn gan-an nígbà tó wà láyé. Kódà, ó nífẹ̀ẹ́ wa débi pé ó fi ẹ̀mí ẹ̀ lélẹ̀ nítorí wa. (Mátíù 20:28; Jòhánù 15:13) Láìpẹ́, Jésù tún máa fi ìfẹ́ tó ní sí wa hàn ní ti pé ó máa lo agbára rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ọba Ìjọba Ọlọ́run láti “fòpin sí ogun kárí ayé.”​—Sáàmù 46:9.

Ẹ gbọ́ ohun tí Bíbélì sọ pé Jésù máa ṣe:

  • “Yóò gba àwọn aláìní tó ń kígbe fún ìrànlọ́wọ́ sílẹ̀, yóò sì gba tálákà àti ẹni tí kò ní olùrànlọ́wọ́. Yóò ṣàánú aláìní àti tálákà, yóò sì gba ẹ̀mí àwọn tálákà là. Yóò gbà wọ́n lọ́wọ́ ìnira àti ìwà ipá.”​—Sáàmù 72:12-14.

Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọrírì ohun tí Jésù ti ṣe fún wa àtohun tó ṣì máa ṣe fún wa? Ohun kan tá a lè ṣe ni pé ká túbọ̀ kẹ́kọ̀ọ́ nípa “ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run” tí Jésù wàásù nígbà tó wà láyé. (Lúùkù 4:43) Kó o lè mọ̀ sí i, ka àpilẹ̀kọ náà “Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́