ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mrt àpilẹ̀kọ 108
  • Jésù Máa Fòpin sí Ipò Òṣì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jésù Máa Fòpin sí Ipò Òṣì
  • Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jésù Máa Fòpin sí Ogun
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Máa Ṣàánú Àwọn Tálákà Bí Jésù Ti Ṣe
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Jésù Máa Fòpin sí Ìwà Ìkà
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Ta Lo Lè Fọkàn Tán?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
Àwọn Míì
Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
mrt àpilẹ̀kọ 108
Ọwọ́ ẹnì kan tó ń tọrọ bárà.

panitan/stock.adobe.com

Jésù Máa Fòpin sí Ipò Òṣì

Nígbà tí Jésù wà láyé, ó nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn gan-an pàápàá àwọn aláìní àtàwọn tó ń jìyà. (Mátíù 9:36) Kódà, ó fi ẹ̀mí ẹ̀ lélẹ̀ nítorí wa. (Mátíù 20:28; Jòhánù 15:13) Láìpẹ́, Jésù tún máa fi hàn pé òun nífẹ̀ẹ́ wa nígbà tó bá lo àṣẹ tó ní gẹ́gẹ́ bí Ọba Ìjọba Ọlọ́run láti fòpin sí ipò òṣì kárí ayé.

Bíbélì lo àwọn ọ̀rọ̀ ewì láti ṣàlàyé ohun tí Jésù máa ṣe, ó ní:

  • “Kí ó gbèjà àwọn tó jẹ́ aláìní, kí ó gba àwọn ọmọ òtòṣì là.”—Sáàmù 72:4.

Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì ohun tí Jésù ti ṣe fún wa àtohun tó ṣì máa ṣe lọ́jọ́ iwájú? Ohun kan tá a lè ṣe ni pé ká gbìyànjú láti mọ púpọ̀ sí i nípa “ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run.” Ìhìn rere yìí náà sì ni Jésù wàásù nígbà tó wà láyé. (Lúùkù 4:43) Ka àpilẹ̀kọ náà, “Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́