ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwfq àpilẹ̀kọ 3
  • Ṣé ẹ gbà pé ẹ̀sìn yín nìkan lẹ̀sìn tòótọ́?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé ẹ gbà pé ẹ̀sìn yín nìkan lẹ̀sìn tòótọ́?
  • Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣé Oríṣiríṣi Ọ̀nà Tó Lọ Sọ́dọ̀ Ọlọ́run Ni Àwọn Ìsìn Jẹ́?
    Jí!—2001
  • Ṣé Gbogbo Ìsìn ni Ìsìn Tòótọ́?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Isin Eyikeyii Ha Dara Tó Bi?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
  • Ṣé Gbogbo Ẹ̀sìn Ni Inú Ọlọ́run Dùn Sí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
Àwọn Míì
Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
ijwfq àpilẹ̀kọ 3
Ẹlẹ́rìí Jèhófà rèé, ó ń wàásù

Ṣé ẹ gbà pé ẹ̀sìn yín nìkan lẹ̀sìn tòótọ́?

Àwọn tí wọ́n bá fi ọwọ́ pàtàkì mú ẹ̀sìn ní láti gbà pé Ọlọ́run àti Jésù fara mọ́ ẹ̀sìn wọn. Ká ní wọn kò gbà bẹ́ẹ̀ ni, ṣé wọ́n á máa ṣe é?

Jésù Kristi kò fara mọ́ èrò àwọn kan pé ọ̀pọ̀ ẹ̀sìn tàbí ọ̀pọ̀ ọ̀nà ló wà, pé gbogbo wọn ló máa ṣamọ̀nà sí ìgbàlà. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó sọ pé: “Tóóró ni ẹnubodè náà, híhá sì ni ojú ọ̀nà tí ó lọ sínú ìyè, díẹ̀ sì ni àwọn tí ń rí i.” (Mátíù 7:14) Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà gbà pé wọ́n ti rí ọ̀nà yẹn. Bí kì í bá ṣe bẹ́ẹ̀ ni, wọn ì bá ti wá ẹ̀sìn míì.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́