ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwfq àpilẹ̀kọ 6
  • Ǹjẹ́ Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jésù?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ǹjẹ́ Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jésù?
  • Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Ni Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Gbọ́?
    Kí Ni Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Gbọ́?
  • “Ọ̀nà àti Òtítọ́ àti Ìyè”
    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn”
  • Ta Ni Jésù Kristi?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • Ta Ni Jésù Kristi?
    Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?
Àwọn Míì
Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
ijwfq àpilẹ̀kọ 6
Jésù rèé nígbà tó ń kú lọ

Ǹjẹ́ Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jésù?

Bẹ́ẹ̀ ni. A ní ìgbàgbọ́ nínú Jésù, tó sọ pé: “Èmi ni ọ̀nà àti òtítọ́ àti ìyè. Kò sí ẹni tí ń wá sọ́dọ̀ Baba bí kò ṣe nípasẹ̀ mi.” (Jòhánù 14:6) A nígbàgbọ́ pé ọ̀run ni Jésù ti wá sáyé àti pé ó fi ìwàláàyè rẹ̀ pípé lélẹ̀ láti fi rà wá pa dà. (Mátíù 20:28) Ikú rẹ̀ àti àjíǹde rẹ̀ mú kó ṣeé ṣe fún àwọn tó bá ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀ láti ní ìyè àìnípẹ̀kun. (Jòhánù 3:16) A tún gbà gbọ́ pé Jésù ti di Ọba Ìjọba Ọlọ́run tó wà lókè ọ̀run, èyí tó máa mú àlááfíà wá bá gbogbo aráyé láìpẹ́. (Ìṣípayá 11:15) Àmọ́, a fara mọ́ ohun tí Jésù sọ pé: “Baba tóbi jù mí lọ.” (Jòhánù 14:28) Nítorí náà, a kì í jọ́sìn Jésù torí a kò gbà pé òun ni Ọlọ́run Olódùmarè.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́