ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwbq àpilẹ̀kọ 20
  • Ṣé Ọlọ́run Ló Fa Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ọlọ́run Ló Fa Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé?
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun tí Bíbélì sọ
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2017
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2020
  • Ìbéèrè Kẹta: Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Jẹ́ Kí Ìyà Máa Jẹ Mí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Àǹfààní Wà Nínú Kéèyàn Fara Da Ìjìyà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
Àwọn Míì
Ohun Tí Bíbélì Sọ
ijwbq àpilẹ̀kọ 20
Ọkùnrin ń tu ẹnì kan nínú

Ṣé Ọlọ́run Ló Fa Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé?

Ohun tí Bíbélì sọ

Bíbélì sọ pé Ọlọ́run kọ́ ló fa ìjìyà! Ìyà kò sí lára ohun tí Jèhófà Ọlọ́run fẹ́ fún aráyé. Àmọ́, tọkọtaya àkọ́kọ́ ṣọ̀tẹ̀ sí ìṣàkóso Ọlọ́run, wọ́n sì fẹ́ láti máa dá pinnu pé ohun kan ló dára tàbí ohun kan ló burú. Wọ́n kọ ẹ̀yìn sí Ọlọ́run wọ́n sì jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Àwa lónìí ń jìyà ohun burúkú tí wọ́n ṣe. Ṣùgbọ́n Ọlọ́run kọ́ ló fa ìyà tó ń jẹ aráyé. Bíbélì sọ pé: “Nígbà tí ẹnikẹ́ni bá wà lábẹ́ àdánwò, kí ó má ṣe sọ pé: ‘Ọlọ́run ni ó ń dán mi wò.’ Nítorí a kò lè fi àwọn ohun tí ó jẹ́ ibi dán Ọlọ́run wò, bẹ́ẹ̀ ni òun fúnra rẹ̀ kì í dán ẹnikẹ́ni wò.” (Jákọ́bù 1:13) Ìpọ́njú lè bá ẹnikẹ́ni, títí kan àwọn tí Ọlọ́run ṣojú rere sí pàápàá.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́