ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwbq àpilẹ̀kọ 27
  • Kí Ni Mo Lè Gbàdúrà Fún?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Ni Mo Lè Gbàdúrà Fún?
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Àǹfààní Pàtàkì Ni Àdúrà Jẹ́
    Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?
  • Sísún Mọ́ Ọlọrun Nínú Àdúrà
    Kí Ni Ọlọ́run Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?
  • Ṣé Àdúrà Olúwa Ni Àdúrà Tó Dáa Jù Láti Gbà?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Máa Gbàdúrà Kó O Lè Túbọ̀ Sún Mọ́ Ọlọ́run
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
Àwọn Míì
Ohun Tí Bíbélì Sọ
ijwbq àpilẹ̀kọ 27

Kí Ni Mo Lè Gbàdúrà Fún?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kò sóhun tó ò lè gbàdúrà fún tó bá ṣáà ti bá ìfẹ́ Ọlọ́run mu, bó ṣe wà nínú Bíbélì. “Ohun yòówù tí ì báà jẹ́ tí a bá béèrè ní ìbámu pẹ̀lú ìfẹ́ rẹ̀, ó ń gbọ́ tiwa.” (1 Jòhánù 5:14) Ṣó o lè sọ ohun tó ń dùn ẹ́ lọ́kàn fún Ọlọ́run? Bẹ́ẹ̀ ni. Bíbélì ṣáà sọ pé: “Ẹ tú ọkàn-àyà yín jáde níwájú [Ọlọ́run].”—Psalm 62:8.

Àpẹẹrẹ ohun tó o lè gbàdúrà fún

  • Ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run.—Lúùkù 17:5.

  • Kí ẹ̀mí mímọ́, tàbí agbára Ọlọ́run, ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti ṣe ohun tó tọ́.—Lúùkù 11:13.

  • Okun láti kojú ìṣòro, kó o sì dènà inúnibíni.—Fílípì 4:13.

  • Ìbalẹ̀ Ọkàn àti àlàáfíà.—Fílípì 4:6, 7.

  • Ọgbọ́n láti ṣe ìpinnu tó tọ́.—Jákọ́bù 1:5.

  • Oúnjẹ́ Òòjọ́.—Mátíù 6:11.

  • Ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀.—Mátíù 6:12.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́