ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwfq àpilẹ̀kọ 25
  • Ṣé Ó Láwọn Fíìmù, Ìwé Tàbí Orin Tẹ́ Ò Gbọ́dọ̀ Gbádùn?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ó Láwọn Fíìmù, Ìwé Tàbí Orin Tẹ́ Ò Gbọ́dọ̀ Gbádùn?
  • Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Yan Eré Ìnàjú Táá Múnú Jèhófà Dùn
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Bó O Ṣe Lè Yan Eré Ìnàjú Tó Gbámúṣé
    ‘Ẹ Dúró Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run’
  • Fọgbọ́n Yan Eré Ìnàjú Tí Wàá Máa Ṣe
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Jẹ́ Amẹ̀tọ́mẹ̀yẹ Bí O Bá Ń Yan Eré Ìnàjú
    Jí!—1998
Àwọn Míì
Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
ijwfq àpilẹ̀kọ 25
Ọ̀dọ́kùnrin kan ń gbọ́ orin látinú ẹ̀rọ tó fi sétí, ó sì tún ń wo àwo orin tó wà lọ́wọ́ rẹ̀.

Ṣé Ó Láwọn Fíìmù, Ìwé Tàbí Orin Tẹ́ Ò Gbọ́dọ̀ Gbádùn?

Rárá. A kì í ṣòfin nípa irú fíìmù táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń wò, ìwé tá à ń kà tàbí irú orin tá à ń tẹ́tí sí. Kí nìdí?

Bíbélì gba ẹnì kọ̀ọ̀kan wa níyànjú pé kí á kọ́ “agbára ìwòye” wa ká lè fi ìyàtọ̀ sáàárín ohun tó tọ́ àti ohun tí kò tọ́.​—Hébérù 5:14.

Àwọn ìlànà kan wà nínú Ìwé Mímọ́ táá jẹ́ kí Kristẹni kọ̀ọ̀kan mọ irú eré ìnàjú tó máa yàn.a Nínú gbogbo ohun tá à ń ṣe nígbèésí ayé, a máa ń “wádìí dájú ohun tí Olúwa tẹ́wọ́ gbà.”​—Éfésù 5:10.

Bíbélì jẹ́ kó ṣe kedere pé àwọn olórí ìdílé láṣẹ déwọ̀n àyè kan lórí ìdílé wọn. Torí náà, wọ́n lè pinnu irú eré ìnàjú táwọn ìdílé wọn máa wò àtèyí tí wọn ò gbọ́dọ̀ wò. (1 Kọ́ríńtì 11:3; Éfésù 6:​1-4) Àmọ́ nínú ìjọ, ẹnikẹ́ni ò láṣẹ láti pinnu ohun táwọn míì máa ṣe. Wọn ò lè ka fíìmù, orin tàbí àwọn òṣèré kan léèwọ̀ fáwọn ará.​—Gálátíà 6:5.

a Bí àpẹẹrẹ, Bíbélì dẹ́bi fún ohunkóhun tó ń gbé ìbẹ́mìílò, ìṣekúṣe tàbí ìwà ipá lárugẹ.​—Diutarónómì 18:​10-13; Éfésù 5:3; Kólósè 3:8.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́