ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ
Ábúráhámù Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run
Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìdí tí Bíbélì fi pe Ábúráhámù ní “ọ̀rẹ́ Jèhófà.” (Jákọ́bù 2:23) Ka ọ̀rọ̀ inú àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.
Ka Ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì tàbí kó o ka èyí tó o wà jáde