ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ
Dáníẹ́lì Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́
Wọ́n mú Dáníẹ́lì kúrò lọ́dọ̀ àwọn òbí rẹ̀. Ṣé ohun tí Jèhófà fẹ́ lá ṣì máa ṣe? Ka àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.
Ka Ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì tàbí kó o ka èyí tó o wà jáde