Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn òǹkọ̀wé míì ni Quadratus, Aristides, Tatian, Apollinaris, Athenagoras, Theophilus, Melito, Minucius Felix àtàwọn míì táwọn èèyàn kò fi bẹ́ẹ̀ mọ̀. Wo Ilé Ìṣọ́ May 15, 2003, ojú ìwé 27 sí 29 àti March 15, 1996, ojú ìwé 28 sí 30.