Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ó ṣeé ṣe kí Pọ́ọ̀lù tọ́ka sí àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ bíi Sáàmù 22:7; 69:21; Aísáyà 50:6; 53:2-7; àti Dáníẹ́lì 9:26.