ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 50
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Àwọn ẹ̀ṣẹ̀ Ísírẹ́lì fa wàhálà (1-3)

      • Ìránṣẹ́ Jèhófà tó jẹ́ onígbọràn (4-11)

        • Ahọ́n àti etí àwọn tí a kọ́ (4)

Àìsáyà 50:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 24:1
  • +2Ọb 17:16, 17
  • +Ais 59:2; Jer 3:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 2/2017, ojú ìwé 1

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 152-153

Àìsáyà 50:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 35:15
  • +Ais 40:28; 59:1
  • +Ẹk 14:21, 29; Sm 106:9; Ais 51:10
  • +Sm 107:33; 114:1, 3; Ais 42:15; Na 1:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 153-157

Àìsáyà 50:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “aṣọ àpò ìdọ̀họ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 10:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 153-156

Àìsáyà 50:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ahọ́n tí a kọ́ dáadáa.”

  • *

    Ní Héb., “fi ọ̀rọ̀.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “fún ẹni tó ti rẹ̀ lókun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 4:11; Jer 1:9
  • +Jo 7:15, 46
  • +Mt 13:54

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 182-183

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2012, ojú ìwé 11

    1/15/2009, ojú ìwé 22

    8/1/1995, ojú ìwé 14-15, 17

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 133

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 157-159

Àìsáyà 50:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 40:6-8
  • +Mt 26:39; Flp 2:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2012, ojú ìwé 11

    1/15/2009, ojú ìwé 22

    8/1/1995, ojú ìwé 15

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 133

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 159

Àìsáyà 50:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn tó fa irùngbọ̀n tu.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 26:67; Mk 14:65; Lk 22:63; Jo 18:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2011, ojú ìwé 14

    1/15/2009, ojú ìwé 21-22

    10/1/2008, ojú ìwé 5

    8/1/1995, ojú ìwé 15

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 133, 172

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 159-161

Àìsáyà 50:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:8
  • +Isk 3:8, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 161

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    8/1/1995, ojú ìwé 15

Àìsáyà 50:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “bá mi fà á.”

  • *

    Tàbí “dojú kọ ara wa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 161-163

Àìsáyà 50:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Kòkòrò.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2009, ojú ìwé 22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 161-163

Àìsáyà 50:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbára lé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:1; 53:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 163-164

Àìsáyà 50:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 164

Àwọn míì

Àìsá. 50:1Di 24:1
Àìsá. 50:12Ọb 17:16, 17
Àìsá. 50:1Ais 59:2; Jer 3:1
Àìsá. 50:2Jer 35:15
Àìsá. 50:2Ais 40:28; 59:1
Àìsá. 50:2Ẹk 14:21, 29; Sm 106:9; Ais 51:10
Àìsá. 50:2Sm 107:33; 114:1, 3; Ais 42:15; Na 1:4
Àìsá. 50:3Ẹk 10:21
Àìsá. 50:4Ẹk 4:11; Jer 1:9
Àìsá. 50:4Jo 7:15, 46
Àìsá. 50:4Mt 13:54
Àìsá. 50:5Sm 40:6-8
Àìsá. 50:5Mt 26:39; Flp 2:8
Àìsá. 50:6Mt 26:67; Mk 14:65; Lk 22:63; Jo 18:22
Àìsá. 50:7Ais 49:8
Àìsá. 50:7Isk 3:8, 9
Àìsá. 50:8Ro 8:33
Àìsá. 50:10Ais 42:1; 53:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 50:1-11

Àìsáyà

50 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

“Ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀+ ìyá yín tí mo lé lọ dà?

Àbí èwo nínú àwọn tí mo jẹ ní gbèsè ni mo tà yín fún?

Ẹ wò ó! Torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín+ ni mo ṣe tà yín,

Mo sì lé ìyá yín lọ torí àwọn àṣìṣe yín.+

 2 Kí ló wá dé tí kò sí ẹnì kankan níbí nígbà tí mo dé?

Kí ló dé tí ẹnì kankan ò dáhùn nígbà tí mo pè?+

Ṣé ọwọ́ mi kúrú jù láti rani pa dà ni,

Àbí mi ò lágbára láti gbani sílẹ̀ ni?+

Wò ó! Mo bá òkun wí, ó sì gbẹ táútáú;+

Mo sọ àwọn odò di aṣálẹ̀.+

Ẹja wọn jẹrà torí kò sí omi,

Wọ́n sì kú torí òùngbẹ.

 3 Mo fi ìṣúdùdù bo ọ̀run,+

Mo sì fi aṣọ ọ̀fọ̀* wọ̀ wọ́n.”

 4 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti fún mi ní ahọ́n àwọn tí a kọ́,*+

Kí n lè mọ bó ṣe yẹ kí n fi ọ̀rọ̀ tó yẹ* dá ẹni tó ti rẹ̀ lóhùn.*+

Ó ń jí mi ní àràárọ̀;

Ó ń jí etí mi kí n lè fetí sílẹ̀ bí àwọn tí a kọ́.+

 5 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti ṣí etí mi,

Mi ò sì ya ọlọ̀tẹ̀.+

Mi ò yíjú sí òdìkejì.+

 6 Mo tẹ́ ẹ̀yìn mi fún àwọn tó ń lù mí,

Mo sì gbé ẹ̀rẹ̀kẹ́ mi fún àwọn tó fa irun tu títí ó fi dán.*

Mi ò fi ojú mi pa mọ́ fún àwọn ohun tó ń dójú tini àti itọ́.+

 7 Àmọ́ Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ máa ràn mí lọ́wọ́.+

Ìdí nìyẹn tí ìtìjú ò fi ní bá mi.

Ìdí nìyẹn tí mo fi ṣe ojú mi bí akọ òkúta,+

Mo sì mọ̀ pé ojú ò ní tì mí.

 8 Ẹni tó ń pè mí ní olódodo wà nítòsí.

Ta ló lè fẹ̀sùn kàn mí?*+

Jẹ́ ká jọ dìde dúró.*

Ta ló fẹ́ bá mi ṣe ẹjọ́?

Kó sún mọ́ mi.

 9 Wò ó! Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ máa ràn mí lọ́wọ́.

Ta ló máa sọ pé mo jẹ̀bi?

Wò ó! Gbogbo wọn máa gbó bí aṣọ.

Òólá* ló máa jẹ wọ́n run.

10 Ta ló bẹ̀rù Jèhófà nínú yín,

Tó sì ń fetí sí ohùn ìránṣẹ́ rẹ̀?+

Ta ló ti rìn nínú òkùnkùn biribiri láìsí ìmọ́lẹ̀ kankan?

Kó gbẹ́kẹ̀ lé orúkọ Jèhófà, kó sì fara ti* Ọlọ́run rẹ̀.

11 “Ẹ wò ó! Gbogbo ẹ̀yin tí ẹ̀ ń dá iná,

Tí ẹ̀ ń mú kí iná ta pàrà,

Ẹ máa rìn nínú ìmọ́lẹ̀ iná yín,

Láàárín iná tí ẹ̀ ń mú kó ta pàrà.

Ohun tí ẹ máa gbà lọ́wọ́ mi nìyí:

Inú ìroragógó lẹ máa dùbúlẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́