Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àkọsílẹ̀ oríṣi àjíǹde mẹ́jọ náà wà nínú 1 Àwọn Ọba 17:17-24; 2 Àwọn Ọba 4:32-37; 13:20, 21; Lúùkù 7:11-17; 8:40-56; Jòhánù 11:38-44; Ìṣe 9:36-42; 20:7-12. Bí ó ṣe ń ka àwọn ìtàn yìí, kíyè sí bó ṣe jẹ́ pé ìṣojú ọ̀pọ̀ èèyàn ni àwọn àjíǹde náà ti wáyé. Ìtàn àjíǹde kẹsàn-án ni ti Jésù Kristi.—Jòhánù 20:1-18.