Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a A lè rí irú àwọn ìránnilétí bẹ́ẹ̀ nínú àwọn àpilẹ̀kọ bíi, “Fi Ọgbọ́n Lo Íńtánẹ́ẹ̀tì” nínú Ilé Ìṣọ́, August 15, 2011, ojú ìwé 3 sí 5 àti “Ṣọ́ra fún Àwọn Ìdẹkùn Èṣù!” àti “Ẹ Dúró Gbọn-in Kẹ́ Ẹ sì Sá fún Àwọn Ohun Tí Sátánì Fi Ń Múni!” nínú Ilé Ìṣọ́, August 15, 2012, ojú ìwé 20 sí 29.