Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Kó o lè rí àwọn ẹsẹ Bíbélì míì tó máa tù ẹ́ nínú, táá sì jẹ́ kó dá ẹ lójú pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ ẹ, wo àkòrí náà “Iyè Méjì” nínú ìwé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́.