March Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, March-April 2023 March 6-12 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Bí Wọ́n Ṣe Ń Jọ́sìn Nínú Tẹ́ńpìlì Túbọ̀ Wà Létòlétò MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bá A Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ Tí Àjálù Bá Ṣẹlẹ̀ March 13-19 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ìmọ̀ràn Onífẹ̀ẹ́ Tí Bàbá Kan Fún Ọmọ Ẹ̀ March 20-26 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ọba Sólómọ́nì Ṣe Ìpinnu Tí Ò Mọ́gbọ́n Dání Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Bíbélì Kíkà Tó Wà fún Ìrántí Ikú Kristi ti Ọdún 2023 March 27–April 2 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Ọkàn Mi Á Máa Wà Níbẹ̀ Nígbà Gbogbo” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ” April 10-16 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ọbabìnrin Ṣébà Mọyì Kéèyàn Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Ka Bíbélì Lójoojúmọ́ Kó O Lè Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n April 17-23 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Tá A Bá Tẹ̀ Lé Ìmọ̀ràn Tó Dáa Ó Máa Ṣe Wá Láǹfààní MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bá A Ṣe Lè Lo Àwọn Fídíò Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì April 24-30 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ìgbà Wo Ló Yẹ Ká Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ