May Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, May-June 2023 May 1-7 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Máa Fi Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àwọn Èèyàn Wò Wọ́n MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wò Ẹ́ Ni Kó O Fi Máa Wo Ara Ẹ May 8-14 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jèhófà Ọlọ́run Yín” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀ De Ìgbà Tí Ọrọ̀ Ajé Máa Dẹnu Kọlẹ̀? May 15-21 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Máa Ń San Àwọn Tó Bá Nígboyà Lẹ́san May 22-28 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Jèhófà Mọ Bó Ṣe Máa Fi Èyí Tó Pọ̀ Ju Bẹ́ẹ̀ San Án Fún Ọ” May 29–June 4 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN O Lè Sin Jèhófà Táwọn Òbí Ẹ Ò Bá Tiẹ̀ Ṣe Bẹ́ẹ̀ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Ni “Bàbá Àwọn Ọmọ Aláìníbaba” June 5-11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ó Dáa Ká Máa Lọ Sípàdé June 12-18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Máa Fún Àwọn Míì Níṣìírí Nígbà Ìṣòro MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Yẹra fún Ẹ̀kọ́ Àwọn Apẹ̀yìndà June 19-25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ṣé Ò Ń Ṣiṣẹ́ Lórí Ohun Tí Ò Ń Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣé O Máa Ń Lo Bíbélì Tá A Gbohùn Rẹ̀ Sílẹ̀? June 26–July 2 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Yọ̀ǹda Ara Ẹ fún Iṣẹ́ Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Kó Máa Yá Ẹ Lára Láti Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀ MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ