January 15 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn” Máa Rí Ìdùnnú Nínú Iṣẹ́ Sísọni Dọmọ Ẹ̀yìn Ǹjẹ́ ‘Ìríjú Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run’ Ni Ọ́? “Èyí Ni Ọ̀nà. Ẹ Máa Rìn Nínú Rẹ̀” Wò ó! Ìránṣẹ́ Tí Jèhófà Tẹ́wọ́ Gbà Ìránṣẹ́ Jèhófà Tí Wọ́n ‘Gún Nítorí Ìrélànàkọjá Wa’ Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ìṣípayá—Apá Kìíní