July 1 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ǹjẹ́ Ìgbésí Ayé Yìí Tiẹ̀ Já Mọ́ Nǹkan Kan? Kí Nìdí Tó Fi Jọ Pé Ìgbésí Ayé Yìí Kò Já Mọ́ Nǹkan Kan? Ìgbésí Ayé Tó Dára—Nísinsìnyí àti Títí Láé Báwo Ni Nǹkan Ṣe Ń Rí Lára Jèhófà? Bíbélì Máa Ń yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? Ó Rí Ìtùnú Gbà Lọ́dọ̀ Ọlọ́run Rẹ̀ Ǹjẹ́ Ọlọ́run Máa Ń Gbé Ẹ̀yà Ìran Kan Ga Ju Òmíràn Lọ? Ta Ló Ṣe Àwọn Òfin Tó Ń Darí Àwọn Nǹkan Tó Wà Lójú Ọ̀run? Ǹjẹ́ O Mọ̀? Bí O Ṣe Lè Dènà Ìdẹwò Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá?